Iroidunnu

Irodunnu jẹ ilé iṣẹ́ agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àti amóhùnmáwòrán ní orí ayélujára, a dáa ile iṣẹ́ yí sílẹ̀ láti máa mú inú gbogbo ọmọ kaaro-o-jiire dùn nípa ṣíṣe ètò ìròyìn onírúurú eré ìdárayá àti orísirísi àwọn ètò alárinrin míràn tí ohùn gbé àṣà àt’èdè Yorùbá larugẹ.

Featured shows

View all shows

Àfihàn Ìgbéayé

Àwọn ohun mère-mère nípa èrò, ìwà, asa àti ètò ìgbáyégbádùn àwa ọmọ Yorùbá.

Latest episodes

Iroidunnu

Subscribe