Motunrayo Oloyede (Hephzibah Muziks) jẹ́ ìránṣẹ́ Ọlọrun, Ajíhìnrere àti Olorin ẹ̀mí tí o kún fún ẹ̀bùn àti ìfàmìòróó Yàn. Lára àwọn orin tí wọ́n ti ṣe ni a ti rí ẸGBE GA, GBOGBO ÒGO, O TOBI.
#OrinTuntun “Ọ̀RỌ̀ ÀSẸ”
Nínú ilé, níbi isẹ́, nínú ọkọ̀ àti ní ibi gbogbo tí ẹ bá wà, Ọ̀RỌ̀ ÀṢẸ jẹ́ orin àsọtẹlẹ ohun rere sínú ayé ènìyàn.
Ẹ tẹ́tí síi kí ẹ di alábùkún fún…