Ìdúpẹ́ òpin ọdún pẹ̀lú Olukoya Ibitoye Olukunle (Sir K Ọba Skoskola) yíò wáyé ní Agogo Márùn Ìrọ̀lẹ́ Ọjọ́ Ìṣẹ́gun, oṣù Kejìlá ọdún yí. Ọ̀pọ̀ àwọn olórin àti àwọn èèyàn pàtàkì ni yóò wà níbẹ̀.
Gbogbo ènìyàn yóò ní anfààní láti gbọ́ ọ ní gbogbo ibi ní àgbáyé lórí Rédíò orí ẹ̀rọ ayélujára Ìróìdunnú Radio.
Ìróìdunnú Radio jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbátẹrù ètò yí.