OBIRIN NI MI_KEMI AKINTAYO_300322

Play episode
Hosted by
John Olatunji

Ẹ tẹ́tí sí ètò OBÌRIN NI MÍ ( I AM A WOMAN) ní alẹ́ òní, lórí Rédíò Ìróidùnnú, ni déédéé Agogo Mẹ́sàn Alẹ́ (Every Wednesday 9PM WAT). Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀ ni atọ́kùn ètò.
Àkòrí ètò tọ̀sẹ̀ yí ni; ÀÌSÒÓTỌ́ AYA SÍ ỌKỌ NÍNÚ ÌGBÉYÀWÓ. (A Wife’s Infidelity In Marriage)
Àlejò wa ni Ọlaitan Olutayọ Aya Dàda.
Ẹ leè gbọ́ ọ níbikíbi tí ẹ bá wà ní àgbáyé lórí ẹ̀rọ ayélujára wa www.iroidunnu.com.
Join the discussion

More from this show

Iroidunnu

Subscribe

Episode 9