(PODCAST) KÍ LÓ N ṢẸLẸ̀?

Play episode
Hosted by
John Olatunji

  • Owo naira ti atijọ kò ṣe ìtẹ́wọ́gbà mọ́ – Ilé iṣẹ́ ìfowópamọ́ àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. CBN
  • Ìjíròro àjọ INEC pẹlú àwọn alákòóso ibùdó ìwọkọ̀ ìpínlẹ̀ Èkó àti ìfẹ̀hónúhàn àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò
  • Ikú àti ifarapa awọn ọmọ ní ilé ìwé olówó nlánlá àti ìgbésẹ ijoba láti dẹ́kun rẹ̀.
  • Orisirisii ìwádìí tí o nsọ nipa ẹnití yíò gbé ‘gbá orókè nínú ìdìbò yan ààrẹ tí onbọ̀. Èwo ni kí a gbàgbọ́ nínú wọn?

Ẹ tẹ́tí sí ètò

Join the discussion

More from this show

Iroidunnu

Subscribe

Episode 13