Nípa Iroidunnu

Irodunnu jẹ ilé iṣẹ́ agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àti amóhùnmáwòrán ní orí ayélujára, a dáa ile iṣẹ́ yí sílẹ̀ láti máa mú inú gbogbo ọmọ kaaro-o-jiire dùn nípa ṣíṣe ètò ìròyìn onírúurú eré ìdárayá àti orísirísi àwọn ètò alárinrin míràn tí ohùn gbé àṣà àt’èdè Yorùbá larugẹ.

Iroidunnu

Subscribe