Ẹ tẹ́tí sí ètò pàtàkì yí…
Ẹ tẹ́tí sí ètò pàtàkì yí…
Owo naira ti atijọ kò ṣe ìtẹ́wọ́gbà mọ́ – Ilé iṣẹ́ ìfowópamọ́ àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. CBN Ìjíròro àjọ INEC pẹlú àwọn alákòóso ibùdó ìwọkọ̀ ìpínlẹ̀ Èkó àti ìfẹ̀hónúhàn àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò Ikú àti ifarapa awọn ọmọ ní ilé ìwé olówó nlánlá...
Ẹ tẹ́tí sí ètò OBÌRIN NI MÍ ( I AM A WOMAN) ní alẹ́ òní, lórí Rédíò Ìróidùnnú, ni déédéé Agogo Mẹ́sàn Alẹ́ (Every Wednesday 9PM WAT). Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀ ni atọ́kùn ètò. Àkòrí ètò tọ̀sẹ̀ yí ni; ÀÌSÒÓTỌ́ AYA SÍ ỌKỌ NÍNÚ ÌGBÉYÀWÓ. (A Wife’s...
KÍNÍ OHUN Tí Ó Ń FÀÁ Tí Ọ̀PỌ̀ ÌPINNU ỌDÚN TUNTUN FI MÁA Ń KÙNÀ? (WHY DO MOST NEW YEAR RESOLUTIONS FAIL?) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀ Ìpinnu fún ọdún tuntun jẹ́ àṣà tí ó wọ́pọ̀ lóde òní, ṣùgbón ìrírí àti ìwádìí ti fihàn...
Ohun tí a ń gbẹ̀yẹ̀wò l’ọ́ṣẹ́ yí ni ẸKỌ́ ÌWÉ TÍ MO KÀ ÀTI ISẸ́ TÍ MO YÀN LÁÀYÒ! Àlejò wa ni Ìyáàfin Ẹgbẹ́yẹmí Mojísọ́lá Àárínọlá.
Lórí Ètò ÌSINMI ALÁYỌ̀ pẹ̀lú Jòhánù Olátúnjí àti Dámilọ́lá Yusuf Tósìn Òní Arábìnrin Tósìn Ọ̀ní jẹ olórin abínibí, ìránṣẹ́ Ọlọ́run, Onígbàgbọ́, onírẹ̀lẹ̀ ajíhìnrere akọrin àti ònkàwé gb’oyè nínú ìmójútó ìmọ̀ ẹ̀rọ ọ́físì. Ó dàgbà sí...
Lórí Ètò AM’ÁIYÉDÙN pẹ̀lú Dámilọ́lá Yusuf (DLOLA)