ShowÌròyìn

Episode 13

(PODCAST) KÍ LÓ N ṢẸLẸ̀?

Owo naira ti atijọ kò ṣe ìtẹ́wọ́gbà mọ́ – Ilé iṣẹ́ ìfowópamọ́ àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. CBN Ìjíròro àjọ INEC pẹlú àwọn alákòóso ibùdó ìwọkọ̀ ìpínlẹ̀ Èkó àti ìfẹ̀hónúhàn àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò Ikú àti ifarapa awọn ọmọ ní ilé ìwé olówó nlánlá...

Episode 1

KÍNÍ OHUN Tí Ó Ń FÀÁ Tí Ọ̀PỌ̀ ÌPINNU ỌDÚN TUNTUN FI MÁA Ń KÙNÀ? (WHY DO MOST NEW YEAR RESOLUTIONS FAIL?) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀

    KÍNÍ OHUN Tí Ó Ń FÀÁ Tí Ọ̀PỌ̀ ÌPINNU ỌDÚN TUNTUN FI MÁA Ń KÙNÀ? (WHY DO MOST NEW YEAR RESOLUTIONS FAIL?) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀     Ìpinnu fún ọdún tuntun jẹ́ àṣà tí ó wọ́pọ̀ lóde òní, ṣùgbón ìrírí àti ìwádìí ti fihàn...

Episode 7

KÍNI ÒFIN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ SỌ NÍPA BÍ A TI ŃṢE ÌGBÉYÀWÓ?

KÍNI ÒFIN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ SỌ NÍPA BÍ A TI ŃṢE ÌGBÉYÀWÓ? Ní àìpẹ́ yí ní ìròyìn kan gbòde kan nípa ìdájọ́ ilé ẹjọ́ gíga ìlú Èkó tí ó sọ wípé gbogbo ìgbéyàwó tí àwọn ènìyàn ṣe ní ìlú Ìkòyí ti di òtúbántẹ́. Ọ̀rọ̀ yí dá rògbòdìyàn sílẹ̀ kí àwọn aṣojú...

Episode 6

ÌDÚPẸ́ ÒPIN ỌDÚN PẸ̀LÚU OLUKỌ̀YÀ ÌBÍTÓYÈ OLÚKÚNLÉ (SIR K ỌBA SKOSKOLA)

Ìdúpẹ́ òpin ọdún pẹ̀lú Olukoya Ibitoye Olukunle (Sir K Ọba Skoskola) yíò wáyé ní Agogo Márùn Ìrọ̀lẹ́ Ọjọ́ Ìṣẹ́gun, oṣù Kejìlá ọdún yí. Ọ̀pọ̀ àwọn olórin àti àwọn èèyàn pàtàkì ni yóò wà níbẹ̀. Gbogbo ènìyàn yóò ní anfààní láti gbọ́ ọ ní gbogbo ibi ní...

Episode 5

ÀWỌN ÀMÌ ÀTI ÌTỌ́JÚ ÀÀRÙN JẸJẸRẸ Ọ̀NÀ TÍ Ó LỌ SÍ ILÉ-ỌMỌ (CERVICAL CANCER) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀

  Ní ìbẹ̀rẹ̀ àmì kankan lè má f’arahàn, ṣùgbón bí ó bá ti ń wọra síi, àwọn àmì wọ̀nyi yíò máa je jáde; Àkọ́kọ́; Tí ìbálòpọ̀ bá ńdun obìrin. Ìkejì; Tí ẹ̀jẹ̀ bá ńti ojú-ara jáde l’êhìn ìbálòpọ̀. Ìkẹ́ta; Rírí ẹ̀jẹ̀ l’ěhìn tí obìrin ti parí nkan...

Iroidunnu

Subscribe