ShowBulọọgi

bulọọgi

Episode 1

KÍNÍ OHUN Tí Ó Ń FÀÁ Tí Ọ̀PỌ̀ ÌPINNU ỌDÚN TUNTUN FI MÁA Ń KÙNÀ? (WHY DO MOST NEW YEAR RESOLUTIONS FAIL?) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀

    KÍNÍ OHUN Tí Ó Ń FÀÁ Tí Ọ̀PỌ̀ ÌPINNU ỌDÚN TUNTUN FI MÁA Ń KÙNÀ? (WHY DO MOST NEW YEAR RESOLUTIONS FAIL?) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀     Ìpinnu fún ọdún tuntun jẹ́ àṣà tí ó wọ́pọ̀ lóde òní, ṣùgbón ìrírí àti ìwádìí ti fihàn...

Episode 7

KÍNI ÒFIN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ SỌ NÍPA BÍ A TI ŃṢE ÌGBÉYÀWÓ?

KÍNI ÒFIN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ SỌ NÍPA BÍ A TI ŃṢE ÌGBÉYÀWÓ? Ní àìpẹ́ yí ní ìròyìn kan gbòde kan nípa ìdájọ́ ilé ẹjọ́ gíga ìlú Èkó tí ó sọ wípé gbogbo ìgbéyàwó tí àwọn ènìyàn ṣe ní ìlú Ìkòyí ti di òtúbántẹ́. Ọ̀rọ̀ yí dá rògbòdìyàn sílẹ̀ kí àwọn aṣojú...

Episode 6

ÌDÚPẸ́ ÒPIN ỌDÚN PẸ̀LÚU OLUKỌ̀YÀ ÌBÍTÓYÈ OLÚKÚNLÉ (SIR K ỌBA SKOSKOLA)

Ìdúpẹ́ òpin ọdún pẹ̀lú Olukoya Ibitoye Olukunle (Sir K Ọba Skoskola) yíò wáyé ní Agogo Márùn Ìrọ̀lẹ́ Ọjọ́ Ìṣẹ́gun, oṣù Kejìlá ọdún yí. Ọ̀pọ̀ àwọn olórin àti àwọn èèyàn pàtàkì ni yóò wà níbẹ̀. Gbogbo ènìyàn yóò ní anfààní láti gbọ́ ọ ní gbogbo ibi ní...

Episode 5

ÀWỌN ÀMÌ ÀTI ÌTỌ́JÚ ÀÀRÙN JẸJẸRẸ Ọ̀NÀ TÍ Ó LỌ SÍ ILÉ-ỌMỌ (CERVICAL CANCER) – Olúwakẹ́mi Akíntáyọ̀

  Ní ìbẹ̀rẹ̀ àmì kankan lè má f’arahàn, ṣùgbón bí ó bá ti ń wọra síi, àwọn àmì wọ̀nyi yíò máa je jáde; Àkọ́kọ́; Tí ìbálòpọ̀ bá ńdun obìrin. Ìkejì; Tí ẹ̀jẹ̀ bá ńti ojú-ara jáde l’êhìn ìbálòpọ̀. Ìkẹ́ta; Rírí ẹ̀jẹ̀ l’ěhìn tí obìrin ti parí nkan...

Episode 2

GBEMISỌ́LÁ Ọ̀SỌJÀ; AṢOJÚ JÉSÙ KRISTÌ KÁÀKIRI ÀGBÁYÉ

Gbémi Ọ̀sọja tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Ilẹ̀olúji ti ìpínlẹ̀ Òndó ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Gbémi jẹ́ Ajíhìnrere, Akọrin àti Olùdarí ìyìn èyí tí ìlépa rẹ̀ jẹ́ láti ṣe aṣojú kristi káàkiri gbogbo àgbáyé. Ó jẹ́ akẹ́kọ́ gb’oyè ní ilé ìwé ìmọ ẹ̀rọ ti ìpínlẹ̀...

Iroidunnu

Subscribe