Lórí Ètò ÌSINMI ALÁYỌ̀ pẹ̀lú Jòhánù Olátúnjí àti Dámilọ́lá Yusuf Tósìn Òní Arábìnrin Tósìn Ọ̀ní jẹ olórin abínibí, ìránṣẹ́ Ọlọ́run...
Latest episodes
Lórí Ètò AM’ÁIYÉDÙN pẹ̀lú Dámilọ́lá Yusuf (DLOLA)
Gbémi Ọ̀sọja tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Ilẹ̀olúji ti ìpínlẹ̀ Òndó ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Gbémi jẹ́ Ajíhìnrere, Akọrin àti Olùdarí ìyìn èyí tí ìlépa...
Ni àìpẹ yí ni Aya mi bi mí wípé? Kínní èrèdí tí wọn fi n má ń sọ wípé “Ìya ni wúrà, baba ni jígí”? Tòótọ, ọ̀rọ̀ yí ti wà ní ẹnu...
Ọ̀gbẹ́ni Délé Àjàyí èyí tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ ( Wamilele ) jẹ́ ẹni tí ọ ma ń fi orin ìyìn fa ọkan awọn ènìyàn súnmọ́ Ọlọ́run, ó sí jẹ́ ẹni...